Odetola -  - Ibadan
Odetola -  - Ibadan

Odetola

  • Rate TSh 7,943
  • Response 1h
Odetola -  - Ibadan

TSh 7,943/hr

Se ofe ni imo ijinle nine ede yoruba? Je ki nran e lowo.

Lesson location

    • Online

About Odetola

Omo yoruba ni mi. Mo mo bi ati nko pelu ka ede yoruba. Ile yi ni abisi. Asa ati ise yoruba je ohun ti dun pupo. Idunu mi lati ran e lowo ki iwo naa le ni oye sii nipa ede yoruba

See more

About the lesson

  • All Levels
  • English

All languages in which the lesson is available :

English

Ilana eko mi yi o dalori sise apere, ibeere ati idahun, maama se alaye awon ohun ti oruju nipa sise apejuwe ni ona ti ororun fun akeko lati ni oye ohun ti o nko. Maasi ma farabale lati gbo ibeere akeko. Kosi ibeere asiwere.

See more

Rates

Rate

  • TSh 7,943

Pack prices

  • 5h: TSh 35
  • 10h: TSh 70

online

  • TSh7,943/h

Similar teachers in Ibadan